Kronika Keji 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn iyawo rẹ ṣoríire. Àwọn òṣìṣẹ́ rẹ tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ nígbà gbogbo tí wọn ń gbọ́ ọ̀rọ̀ ọgbọ́n rẹ náà ṣoríire.

Kronika Keji 9

Kronika Keji 9:4-14