Kronika Keji 9:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni jọba lórí àwọn ọba gbogbo, láti odò Yufurate títí dé ilẹ̀ àwọn ará Filistia ati títí dé ààlà Ijipti.

Kronika Keji 9

Kronika Keji 9:24-27