Kronika Keji 9:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Wúrà ni wọ́n fi ṣe gbogbo ife Solomoni, ati gbogbo ohun èlò tí ó wà ní ilé Igbó Lẹbanoni. Fadaka kò jámọ́ nǹkankan ní àkókò ìjọba Solomoni.

Kronika Keji 9

Kronika Keji 9:18-24