Kronika Keji 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni fi wúrà tí a fi òòlù lù ṣe igba (200) apata ńláńlá. Ìwọ̀n wúrà tí ó lò fún ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ẹgbẹta (600) ṣekeli.

Kronika Keji 9

Kronika Keji 9:5-17