Kronika Keji 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ ìlú Beti Horoni ti òkè ati Beti Horoni ti ìsàlẹ̀. Wọ́n jẹ́ ìlú olódi, wọ́n ní ìlẹ̀kùn ati ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn,

Kronika Keji 8

Kronika Keji 8:4-12