Kronika Keji 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olórí lára àwọn òṣìṣẹ́ Solomoni jẹ́ igba ati aadọta (250), àwọn ni wọ́n ń ṣe àkóso àwọn tí wọn ń ṣiṣẹ́.

Kronika Keji 8

Kronika Keji 8:6-11