Kronika Keji 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo bá sé ojú ọ̀run, tí òjò kò bá rọ̀, tabi tí mo pàṣẹ fún eṣú láti ba oko jẹ́, tabi tí mo rán àjàkálẹ̀ àrùn sí ààrin àwọn eniyan mi,

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:11-21