Kronika Keji 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó ní, “Ẹni ìyìn ni OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ó mú ohun gbogbo tí ó wí fún Dafidi, baba mi, ṣẹ fúnrarẹ̀, nítorí ó wí pé,

Kronika Keji 6

Kronika Keji 6:3-9