Kronika Keji 6:15 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti mú ìlérí rẹ ṣẹ fún baba mi, Dafidi, iranṣẹ rẹ. O fi ẹnu rẹ ṣèlérí, o sì ti fi ọwọ́ ara rẹ mú ìlérí náà ṣẹ lónìí.

Kronika Keji 6

Kronika Keji 6:10-25