Kronika Keji 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Solomoni dúró níwájú pẹpẹ lójú gbogbo eniyan, ó gbé ọwọ́ mejeeji sókè, ó sì gbadura sí Ọlọrun.

Kronika Keji 6

Kronika Keji 6:3-18