Kronika Keji 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀pá náà gùn tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi lè rí orí wọn láti ibi mímọ́ jùlọ, ṣugbọn wọn kò lè rí wọn láti ìta. Wọ́n wà níbẹ̀ títí di òní olónìí.

Kronika Keji 5

Kronika Keji 5:1-10