Kronika Keji 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn onífèrè ati àwọn akọrin pa ohùn pọ̀ wọ́n ń kọ orin ìyìn ati orin ọpẹ́ sí OLUWA). Wọ́n ń fi fèrè ati ìlù ati àwọn ohun èlò orin mìíràn kọrin ìyìn sí OLUWA pé:“OLUWA ṣeun,ìfẹ́ ńlá Rẹ̀ kò lópin.”Ìkùukùu kún inú tẹmpili OLUWA,

Kronika Keji 5

Kronika Keji 5:9-14