Kronika Keji 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbada náà nípọn tó ìbú àtẹ́lẹwọ́, etí rẹ̀ dàbí etí ife omi ati bí òdòdó lílì. Agbada náà gbà tó ẹgbẹẹdogun ìwọ̀n bati omi.

Kronika Keji 4

Kronika Keji 4:2-9