Kronika Keji 36:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoiakini jẹ́ ọmọ ọdún mẹjọ nígbà tí ó jọba. Ó wà lórí oyè fún oṣù mẹta ati ọjọ́ mẹ́wàá ní Jerusalẹmu. Ohun tí ó ṣe burú lójú OLUWA.

Kronika Keji 36

Kronika Keji 36:3-13