Kronika Keji 36:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebukadinesari, ọba Babiloni, kó ninu àwọn ohun èlò ilé OLUWA lọ sí Babiloni, ó kó wọn sinu ààfin rẹ̀ ní Babiloni.

Kronika Keji 36

Kronika Keji 36:2-14