Kronika Keji 36:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n jó ilé OLUWA, wọ́n wó odi Jerusalẹmu, wọ́n jó ààfin ọba, wọ́n sì ba gbogbo nǹkan olówó iyebíye ibẹ̀ jẹ́.

Kronika Keji 36

Kronika Keji 36:17-23