Kronika Keji 36:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mọkanlelogun ni Sedekaya nígbà tí ó jọba. Ó wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla.

Kronika Keji 36

Kronika Keji 36:3-12