Kronika Keji 35:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii Jeremaya kọ orin arò fún Josaya ọba. Ó ti di àṣà ní Israẹli fún àwọn akọrin, lọkunrin ati lobinrin láti máa mẹ́nu ba Josaya nígbàkúùgbà tí wọ́n bá ń kọrin arò.

Kronika Keji 35

Kronika Keji 35:23-27