Kronika Keji 35:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wá ṣe àsè Àjọ Ìrékọjá, wọ́n sì ṣe Àjọ Àìwúkàrà fún ọjọ́ meje.

Kronika Keji 35

Kronika Keji 35:13-23