Kronika Keji 35:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí gbogbo ètò ti parí, àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi dúró ní ààyè wọn gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí ọba pa.

Kronika Keji 35

Kronika Keji 35:9-15