Kronika Keji 34:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni ó ṣe ní àwọn ìlú Manase, ati ti Efuraimu, ati àwọn ìlú ilẹ̀ Simeoni títí dé ilẹ̀ Nafutali, ati ní gbogbo àyíká wọn.

Kronika Keji 34

Kronika Keji 34:1-10