Kronika Keji 33:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Manase ṣi àwọn ará Juda ati Jerusalẹmu lọ́nà, tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi ṣe burúkú ju àwọn orílẹ̀-èdè tí OLUWA parun fún Israẹli lọ.

Kronika Keji 33

Kronika Keji 33:8-15