Kronika Keji 33:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ àwọn eniyan ṣì ń rúbọ ní àwọn ibi ìrúbọ, ṣugbọn OLUWA Ọlọrun wọn ni wọ́n ń rúbọ sí.

Kronika Keji 33

Kronika Keji 33:12-25