Kronika Keji 33:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ ọdún mejila ni Manase nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún marundinlọgọta.

Kronika Keji 33

Kronika Keji 33:1-6