Kronika Keji 32:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, nígbà tí Senakeribu ati àwọn ogun rẹ̀ gbógun ti Lakiṣi, ó ranṣẹ sí Hesekaya ọba Juda ati àwọn ará Juda tí wọ́n wà ní Jerusalẹmu pé,

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:3-13