Kronika Keji 32:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó ọpọlọpọ eniyan jọ, wọ́n dí àwọn orísun omi ati àwọn odò tí ń ṣàn ní ilẹ̀ náà. Wọ́n ní, “Kò yẹ kí ọba Asiria wá, kí ó bá omi tí ó tó báyìí.”

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:3-11