Kronika Keji 32:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà, ó kọ́ ọpọlọpọ ìlú fún ara rẹ̀, ó sì ní agbo ẹran lọpọlọpọ, nítorí Ọlọrun ti fún un ní ọrọ̀ lọpọlọpọ.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:24-33