Kronika Keji 32:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe gba Hesekaya ati àwọn ará Jerusalẹmu sílẹ̀ lọ́wọ́ Senakeribu, ọba Asiria, ati gbogbo àwọn ọ̀tá Hesekaya, ó sì fún un ní alaafia.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:12-30