Kronika Keji 32:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ̀rọ̀ Ọlọrun Jerusalẹmu gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn oriṣa àtọwọ́dá tí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ń bọ.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:14-25