Kronika Keji 32:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní èwo ni oriṣa wọn gbà sílẹ̀ lọ́wọ́ òun, ninu gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi tí baba òun parun, tí Ọlọrun tiyín yóo fi wá gbà yín?

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:9-21