Kronika Keji 32:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní bí Hesekaya bá ní OLUWA Ọlọrun wọn yóo gbà wọ́n lọ́wọ́ òun ọba Asiria, ó ń ṣì wọ́n lọ́nà ni, ó fẹ́ kí òùngbẹ ati ebi pa wọ́n kú ni.

Kronika Keji 32

Kronika Keji 32:6-20