Kronika Keji 31:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Jákèjádò Juda ni Hesekaya ti ṣe ètò yìí, ó ṣe ohun tí ó dára, tí ó tọ́, tí ó sì jẹ́ òtítọ́ lójú OLUWA Ọlọrun rẹ̀.

Kronika Keji 31

Kronika Keji 31:18-21