Kronika Keji 30:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọn kò lè ṣe é ní àkókò rẹ̀ nítorí àwọn alufaa tí wọ́n ti ya ara wọn sí mímọ́ kò tíì pọ̀ tó, àwọn eniyan kò sì tíì péjọ sí Jerusalẹmu tán.

Kronika Keji 30

Kronika Keji 30:1-4