Kronika Keji 30:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo Jerusalẹmu kún fún ayọ̀ nítorí kò tíì tún sí irú rẹ̀ mọ́ láti ìgbà Solomoni, ọmọ Dafidi, ọba Israẹli.

Kronika Keji 30

Kronika Keji 30:17-27