Kronika Keji 30:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn tún pinnu láti pa àjọ náà mọ́ fún ọjọ́ meje sí i, wọ́n sì fi tayọ̀tayọ̀ ṣe é.

Kronika Keji 30

Kronika Keji 30:17-25