Kronika Keji 30:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọn kò tíì ya ara wọn sí mímọ́ pọ̀ níbi àpéjọ náà, nítorí náà, àwọn ọmọ Lefi bá wọn pa ẹran wọn kí àwọn ẹran náà lè jẹ́ mímọ́ fún OLUWA.

Kronika Keji 30

Kronika Keji 30:10-21