Kronika Keji 30:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun lọ́wọ́ sí ohun tí àwọn ará Juda ń ṣe, ó fi sí wọn ní ọkàn láti mú àṣẹ tí ọba ati àwọn olórí pa fún wọn ṣẹ, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLUWA.

Kronika Keji 30

Kronika Keji 30:11-22