Kronika Keji 29:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ati ìjọ eniyan yọ̀ nítorí ohun tí Ọlọrun ṣe fún wọn, nítorí láìròtẹ́lẹ̀ ni gbogbo rẹ̀ bẹ̀rẹ̀.

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:30-36