Kronika Keji 29:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba ati ìjọ eniyan bá bẹ̀rẹ̀ sí sin OLUWA, àwọn akọrin ń kọrin, àwọn afunfèrè ń fun fèrè títí tí ẹbọ sísun náà fi parí.

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:20-29