Kronika Keji 29:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà wọ́n kó àwọn òbúkọ fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ wá sọ́dọ̀ ọba ati ìjọ eniyan, wọ́n sì gbé ọwọ́ lé wọn lórí.

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:18-29