Kronika Keji 29:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá kó àwọn arakunrin wọn jọ, wọ́n sì ya ara wọn sí mímọ́. Wọ́n wọ ilé OLUWA láti tọ́jú rẹ̀ bí ọba ti pa á láṣẹ, gẹ́gẹ́ bí òfin OLUWA.

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:12-19