Kronika Keji 29:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya jọba ní Juda nígbà tí ó di ẹni ọdún mẹẹdọgbọn; ó sì wà lórí oyè fún ọdún mọkandinlọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Abija, ọmọ Sakaraya.

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:1-11