Kronika Keji 28:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rúbọ, ó sun turari ní àwọn ibi ìrúbọ, ati lórí òkè káàkiri ati lábẹ́ gbogbo igi tútù.

Kronika Keji 28

Kronika Keji 28:1-9