Kronika Keji 28:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasi kó ohun ìṣúra inú ilé OLUWA, ati ti ààfin, ati ti inú ilé àwọn ìjòyè, ó fi san ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba Asiria, sibẹsibẹ ọba Asiria kò ràn án lọ́wọ́.

Kronika Keji 28

Kronika Keji 28:16-27