Kronika Keji 28:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn ọmọ ogun náà dá àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú ati ẹrù tí wọn ń kó bọ̀ sílẹ̀ níwájú àwọn ìjòyè ati gbogbo ìjọ eniyan Israẹli.

Kronika Keji 28

Kronika Keji 28:11-16