Kronika Keji 28:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọ́ tèmi, ẹ dá àwọn arakunrin yín tí ẹ ti kó lẹ́rú pada, nítorí ibinu OLUWA wà lórí yín.”

Kronika Keji 28

Kronika Keji 28:1-13