Kronika Keji 27:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yòókù tí Jotamu ṣe ati àwọn ogun tí ó jà, ati àwọn nǹkan mìíràn tí ó tún ṣe ni a kọ sinu ìwé àwọn ọba Israẹli ati ti Juda.

Kronika Keji 27

Kronika Keji 27:1-9