Kronika Keji 27:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ àwọn ìlú ní agbègbè olókè Juda ó sì kọ́ ibi ààbò ati ilé-ìṣọ́ ninu igbó lára òkè.

Kronika Keji 27

Kronika Keji 27:1-9