Kronika Keji 26:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sin Ọlọrun nígbà ayé Sakaraya, nítorí pé Sakaraya ń kọ́ ọ ní ìbẹ̀rù Ọlọrun. Ní gbogbo àkókò tí ó fi ń sin Ọlọrun, Ọlọrun bukun un.

Kronika Keji 26

Kronika Keji 26:1-15