Kronika Keji 26:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ ọdún mẹrindinlogun ni Usaya nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mejilelaadọta. Jekolaya, ará Jerusalẹmu ni ìyá rẹ̀.

Kronika Keji 26

Kronika Keji 26:1-4